Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 13:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Nígbà tí ó sì ti gbà òkèlè náà tan, ó jáde lójúkan náà àkókò náà si jẹ òru.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

30 Lẹsẹkẹsẹ tí Judasi ti gba òkèlè náà tán, ó jáde lọ. Ilẹ̀ ti ṣú nígbà náà.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

30 Nigbati o si ti gbà òkele na tan, o jade lojukanna: oru si ni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 13:30
6 Iomraidhean Croise  

Nítorí wọn kò le sùn àyàfi tí wọ́n bá ṣe ibi, wọn kò ní tòògbé àyàfi tí wọ́n bá gbé ẹlòmíràn ṣubú


Ẹsẹ̀ wọn yára bọ́ sínú ẹ̀ṣẹ̀; wọ́n yára láti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀. Èrò wọn sì jẹ́ èrò ibi; ìparun àti ìdahoro ni ó wà ní ṣíṣe ààmì ọ̀nà wọn.


Nígbà tí èmi wà pẹ̀lú yín lójoojúmọ́ ní tẹmpili, ẹ̀yin kò na ọwọ́ mú mi: ṣùgbọ́n àkókò tiyín ni èyí, àti agbára òkùnkùn n jẹ ọba.”


Nítorí náà Jesu dáhùn pé, “Òun náà ni, ẹni tí mo bá fi àkàrà fún nígbà tí mo bá fi run àwo.” Nígbà tí ó sì fi run ún tan, ó fi fún Judasi Iskariotu ọmọ Simoni.


“Ẹsẹ̀ wọn yára láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀:


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan