Johanu 12:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Jesu sì dáhùn wí pé, “Kì í ṣe nítorí mi ni ohùn yìí ṣe wá, bí kò ṣe nítorí yín. Faic an caibideilYoruba Bible30 Jesu wí fún wọn pé, “Ohùn yìí kò wá nítorí tèmi bí kò ṣe nítorí tiyín. Faic an caibideilBibeli Mimọ30 Jesu si dahùn wipe, Ki iṣe nitori mi li ohùn yi ṣe wá, bikoṣe nitori nyin. Faic an caibideil |