Johanu 12:22 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 Filipi wá, ó sì sọ fún Anderu; Anderu àti Filipi wá, wọ́n sì sọ fún Jesu. Faic an caibideilYoruba Bible22 Filipi lọ sọ fún Anderu, Anderu ati Filipi bá jọ lọ sọ fún Jesu. Faic an caibideilBibeli Mimọ22 Filippi wá, o si sọ fun Anderu; Anderu ati Filippi wá, nwọn si sọ fun Jesu. Faic an caibideil |