Johanu 11:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Jesu kò tí ì wọ ìlú, ṣùgbọ́n ó wà ní ibi kan náà tí Marta ti pàdé rẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible30 (Jesu kò tíì wọ ìlú, ó wà ní ibi tí Mata ti pàdé rẹ̀.) Faic an caibideilBibeli Mimọ30 Jesu kò sá ti iwọ̀ ilu, ṣugbọn o wà nibikanna ti Marta pade rẹ̀. Faic an caibideil |