Johanu 11:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Nígbà tí ó gbọ́, ó dìde lọ́gán, ó sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible29 Bí Maria ti gbọ́, ó dìde kíá, ó bá lọ sọ́dọ̀ Jesu. Faic an caibideilBibeli Mimọ29 Nigbati o gbọ́, o dide lọgan, o si wá sọdọ rẹ̀. Faic an caibideil |