Johanu 11:24 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 Marta wí fún un pé, “Mo mọ̀ pé yóò jíǹde ní àjíǹde ìkẹyìn.” Faic an caibideilYoruba Bible24 Mata dá a lóhùn pé, “Mo mọ̀ pé yóo jí dìde ní ajinde ọjọ́ ìkẹyìn.” Faic an caibideilBibeli Mimọ24 Marta wi fun u pe, Mo mọ̀ pe yio jinde li ajinde nigbẹhin ọjọ. Faic an caibideil |