Johanu 1:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní20 Òun kò sì kùnà láti jẹ́wọ́, ṣùgbọ́n òun jẹ́wọ́ wọ́ọ́rọ́wọ́ pé, “Èmi kì í ṣe Kristi náà.” Faic an caibideilYoruba Bible20 Ó sọ òtítọ́, kò parọ́, ó ní, “Èmi kì í ṣe Mesaya náà.” Faic an caibideilBibeli Mimọ20 O si jẹwọ, kò si sẹ́; o si jẹwọ pe, Emi kì iṣe Kristi na. Faic an caibideil |