Johanu 1:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 Òun ni ó sì wà pẹ̀lú Ọlọ́run ní àtètèkọ́ṣe. Faic an caibideilYoruba Bible2 Òun ni ó wà pẹlu Ọlọrun ní ìbẹ̀rẹ̀, kí á tó dá ayé. Faic an caibideilBibeli Mimọ2 On na li o wà li àtetekọṣe pẹlu Ọlọrun. Faic an caibideil |