Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 8:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Ó sì rán àdàbà kan jáde láti wò ó bóyá omi ti gbẹ kúrò lórí ilẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

8 Ó tún rán ẹyẹ àdàbà kan jáde láti lọ wò ó bóyá omi ti gbẹ lórí ilẹ̀,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

8 O si rán oriri kan jade, lati ọdọ rẹ̀ lọ, ki o wò bi omi ba nfà kuro lori ilẹ;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 8:8
7 Iomraidhean Croise  

Ó sì rán ẹyẹ ìwò kan jáde, tí ó ń fò káàkiri síwá àti sẹ́yìn títí omi fi gbẹ kúrò ní orí ilẹ̀.


Ṣùgbọ́n àdàbà náà kò rí ìyàngbẹ ilẹ̀ bà lé nítorí omi kò tí ì tan lórí ilẹ̀, ó sì padà sọ́dọ̀ Noa. Noa na ọwọ́ rẹ̀ jáde ó sì mú ẹyẹ náà wọlé sọ́dọ̀ ara rẹ̀ nínú ọkọ̀.


Báwo ni o ti lẹ́wà tó, olólùfẹ́ mi! Háà, Báwo ni o ṣe lẹ́wà tó! Ìwọ ní ojú ẹyẹlé.


Àdàbà mi wà nínú pàlàpálá òkúta, ní ibi ìkọ̀kọ̀ ní orí òkè gíga, fi ojú rẹ hàn mí, jẹ́ kí èmi gbọ́ ohùn rẹ; Nítorí tí ohùn rẹ dùn, tí ojú rẹ sì ní ẹwà.


“Mò ń rán yín lọ gẹ́gẹ́ bí àgùntàn sáàrín ìkookò. Nítorí náà, kí ẹ ní ìṣọ́ra bí ejò, kí ẹ sì ṣe onírẹ̀lẹ̀ bí àdàbà.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan