Gẹnẹsisi 8:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 Omi náà sì ń gbẹ si títí di oṣù kẹwàá. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kẹwàá, orí àwọn òkè sì farahàn. Faic an caibideilYoruba Bible5 Omi náà sì ń fà sí i títí di oṣù kẹwaa. Ní ọjọ́ kinni oṣù náà ni ṣóńṣó orí àwọn òkè ńlá hàn síta. Faic an caibideilBibeli Mimọ5 Omi si nfà titi o fi di oṣù kẹwa: li oṣù kẹwa, li ọjọ́ kini oṣù li ori awọn okenla hàn, Faic an caibideil |