Gẹnẹsisi 3:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 Obìnrin náà dá ejò lóhùn pé, “Àwa lè jẹ lára àwọn èso igi tí ó wà nínú ọgbà, Faic an caibideilYoruba Bible2 Obinrin náà dá a lóhùn, ó ní: “A lè jẹ ninu èso àwọn igi tí wọ́n wà ninu ọgbà, Faic an caibideilBibeli Mimọ2 Obinrin na si wi fun ejò na pe, Awa a ma jẹ ninu eso igi ọgbà: Faic an caibideil |