Gẹnẹsisi 26:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Nígbà náà ni Abimeleki wí fún Isaaki pé, “Jáde kúrò ní ilẹ̀ wa, nítorí tí ìwọ ti di alágbára púpọ̀ jù wá lọ.” Faic an caibideilYoruba Bible16 Abimeleki bá wí fún Isaaki pé, “Kúrò lọ́dọ̀ wa, nítorí pé o ti lágbára jù wá lọ.” Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Abimeleki si wi fun Isaaki pe, Lọ kuro lọdọ wa; nitori ti iwọ lagbara pupọ̀ ju wa lọ. Faic an caibideil |