Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 23:3 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Abrahamu sì dìde lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkú aya rẹ̀, ó sì sọ fún àwọn ará Hiti wí pé,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

3 Nígbà tí ó yá, Abrahamu dìde níwájú òkú Sara, ó lọ bá àwọn ará Hiti, ó ní,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Abrahamu si dide kuro niwaju okú rẹ̀, o si sọ fun awọn ọmọ Heti, wipe,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 23:3
9 Iomraidhean Croise  

Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀, àti Heti.


àti ti ará Hiti, àti ti ará Peresi, àti ti ará Refaimu.


Àwọn ọmọ Hiti dá Abrahamu lóhùn pé,


Nígbà náà ni Abrahamu dìde, ó sì tẹríba níwájú àwọn ará ilẹ̀ náà, àwọn ará Hiti.


Inú oko tí Abrahamu rà lọ́wọ́ ara Hiti yìí ni a sin Abrahamu àti Sara aya rẹ̀ sí.


Nígbà náà ni Rebeka wí fún Isaaki pé, “Ayé sì sú mi nítorí àwọn ọmọbìnrin Hiti wọ̀nyí. Bí Jakọbu bá fẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Hiti wọ̀nyí, ó kúkú sàn kí n má wà láààyè.”


Ihò àpáta tí ó wà ní ilẹ̀ Makpela, nítòsí Mamre ní Kenaani, èyí tí Abrahamu rà gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ ìsìnkú lọ́wọ́ Efroni ará Hiti pẹ̀lú ilẹ̀ rẹ̀.


Uriah ará Hiti. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́tà-dínlógójì.


Dafidi sì dáhùn, ó sì wí fún Ahimeleki, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hiti, àti fún Abiṣai ọmọ Seruiah ẹ̀gbọ́n Joabu, pé, “Ta ni yóò ba mi sọ̀kalẹ̀ lọ sọ́dọ̀ Saulu ni ibùdó?” Abiṣai sì wí pé, “Èmi yóò ba ọ sọ̀kalẹ̀ lọ.”


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan