Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 2:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Ṣùgbọ́n ìsun omi ń jáde láti ilẹ̀, ó sì ń bu omi rin gbogbo ilẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

6 Ṣugbọn omi kan a máa ru jáde láti inú ilẹ̀ láti mú kí gbogbo ilẹ̀ rin.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

6 Ṣugbọn ikũku a ti ilẹ wá, a si ma rin oju ilẹ gbogbo.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 2:6
3 Iomraidhean Croise  

Kò sí igi igbó kan ní orí ilẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ewéko igbó kan tí ó tí ì hù jáde ní ilẹ̀, nítorí Olúwa Ọlọ́run kò tí ì rọ̀jò sórí ilẹ̀, kò sì sí ènìyàn láti ro ilẹ̀.


Olúwa Ọlọ́run sì fi erùpẹ̀ ilẹ̀ mọ ènìyàn, ó si mí èémí ìyè sí ihò imú rẹ̀, ènìyàn sì di alààyè ọkàn.


Ó mú ìkùùkuu gòkè láti òpin ilẹ̀ wá: ó dá mọ̀nàmọ́ná fún òjò: ó ń mú afẹ́fẹ́ ti inú ilẹ̀ ìṣúra rẹ̀ wá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan