Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 10:3 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifàti àti Togarma.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣikenasi, Rifati, ati Togama.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Ati awọn ọmọ Gomeri, Aṣkenasi, ati Rifati, ati Togarma.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 10:3
4 Iomraidhean Croise  

Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifàti àti Togarma.


“Gbé àsíá sókè ní ilẹ̀ náà! Fọn ìpè láàrín àwọn orílẹ̀-èdè! Sọ àwọn orílẹ̀-èdè di mímọ́ sórí rẹ̀, pe àwọn ìjọba yìí láti dojúkọ ọ́: Ararati, Minini àti Aṣkenasi. Yan olùdarí ogun láti kọlù ú, rán àwọn ẹṣin sí i bí ọ̀pọ̀ eṣú.


“ ‘Àwọn ti ilé Beti-Togarma ṣe ìpààrọ̀ ẹṣin-ìṣiṣẹ́, ẹṣin ogun àti ìbáaka ṣòwò ní ọjà rẹ.


Gomeri náà pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ-ogun rẹ̀, àti Beti-Togarma láti jìnnàjìnnà àríwá pẹ̀lú gbogbo àwọn ọ̀wọ́ ogun rẹ̀—ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan