Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Daniẹli 6:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Nígbà náà, ni Dariusi ọba fi ọwọ́ sí ìwé àṣẹ náà.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

9 Nítorí náà, Dariusi ọba fi ọwọ́ sí òfin náà, ó sì fi òǹtẹ̀ tẹ̀ ẹ́.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

9 Nigbana ni Dariusi fi ọwọ sinu iwe ati aṣẹ na.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Daniẹli 6:9
6 Iomraidhean Croise  

“Nítorí náà, bí ó bá tọ́ lójú ọba, jẹ́ kí ó gbé àṣẹ ọba jáde, kí ó sì jẹ́ kí ó wà ní àkọsílẹ̀ pẹ̀lú òfin Persia àti Media, èyí tí kò le é parẹ́, pé kí Faṣti kí ó má ṣe wá síwájú ọba Ahaswerusi. Kí ọba sì fi oyè ayaba rẹ̀ fún ẹlòmíràn tí ó sàn jù ú lọ.


Ó dára láti máa gbẹ́kẹ̀lé Olúwa ju à ti gbẹ́kẹ̀lé àwọn ọmọ-aládé lọ.


Ẹ má ṣe ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú àwọn ọmọ-aládé, àní, ọmọ ènìyàn, lọ́wọ́ ẹni tí kò sí ìrànlọ́wọ́.


bí a bá ti fi ọ̀rọ̀ tí ó sọ dẹkùn mú ọ, tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ ti kó ọ sí pàkúté,


Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́, èémí ẹni tó wà ní ihò imú rẹ̀. Nítorí nínú kín ni a lè kà á sí?


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan