Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Daniẹli 6:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Daniẹli sì dáhùn wí pé, “ọba kí ẹ pẹ́!

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

21 Daniẹli dáhùn pé, “Kabiyesi, kí ọba pẹ́,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

21 Nigbana ni Danieli wi fun ọba pe, ki ọba ki o pẹ.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Daniẹli 6:21
5 Iomraidhean Croise  

Ṣùgbọ́n mo wí fún ọba pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! Èéṣe tí ojú mi ko ṣe ní fàro, nígbà tí ìlú tí a sin àwọn baba mi sí wà ní ahoro, tí a sì ti fi iná run àwọn ibodè rẹ̀?”


Nígbà náà ni àwọn awòràwọ̀ dá ọba lóhùn ní èdè Aramaiki pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! Sọ àlá yìí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ àwa yóò sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún ọ.”


Nígbà náà, ni Nebukadnessari dé ẹnu-ọ̀nà iná ìléru, ó sì kígbe pé, “Ṣadraki, Meṣaki àti Abednego, ìránṣẹ́ Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, ẹ jáde, ẹ wá níbi!” Nígbà náà ni Ṣadraki, Meṣaki àti Abednego jáde láti inú iná.


Wọ́n sọ fún ọba Nebukadnessari pé, “Kí ọba kí ó pẹ́.


Nígbà náà ni àwọn alákòóso àti àwọn baálẹ̀ lọ gẹ́gẹ́ bí ikọ̀ sí ọ̀dọ̀ ọba, wọ́n wí pé: “Ìwọ Dariusi ọba, kí o pẹ́!


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan