Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Daniẹli 3:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Wọ́n sọ fún ọba Nebukadnessari pé, “Kí ọba kí ó pẹ́.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

9 “Kí ọba kí ó pẹ́!

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

9 Nwọn dahùn, nwọn si wi fun Nebukadnessari ọba, pe, Ki ọba ki o pẹ́.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Daniẹli 3:9
7 Iomraidhean Croise  

Nígbà náà ni Batṣeba tẹríba, ó sì kúnlẹ̀ níwájú ọba pé, “Kí olúwa mi Dafidi ọba kí ó pẹ́!”


Nígbà náà ni àwọn awòràwọ̀ dá ọba lóhùn ní èdè Aramaiki pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! Sọ àlá yìí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ àwa yóò sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún ọ.”


Nígbà tí ayaba gbọ́ ohùn ọba àti àwọn ọlọ́lá rẹ̀, ó wá ilé àsè wá. Ó wí pé, “Kí ọba kí ó pẹ́! Má ṣe jẹ́ kí inú rẹ bàjẹ́, má sì ṣe jẹ́ kí ojú u rẹ fàro.


Daniẹli sì dáhùn wí pé, “ọba kí ẹ pẹ́!


Nígbà náà ni àwọn alákòóso àti àwọn baálẹ̀ lọ gẹ́gẹ́ bí ikọ̀ sí ọ̀dọ̀ ọba, wọ́n wí pé: “Ìwọ Dariusi ọba, kí o pẹ́!


Ẹ san ohun tí ó tọ́ fún ẹni gbogbo: owó òde fún ẹni tí owó òde í ṣe tirẹ̀: owó bodè fún ẹni tí owó bodè í ṣe tirẹ̀: ẹ̀rù fún ẹni tí ẹ̀rù í ṣe tirẹ̀; ọlá fún ẹni tí ọlá í ṣe tirẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan