Daniẹli 1:14 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní14 Bẹ́ẹ̀ ni ó sì gbà láti dán wọn wò fún ọjọ́ mẹ́wàá. Faic an caibideilYoruba Bible14 Ó gba ohun tí wọ́n wí, ó sì dán wọn wò fún ọjọ́ mẹ́wàá. Faic an caibideilBibeli Mimọ14 Bẹ̃li o gbà fun wọn li ọ̀ran yi, o si dan wọn wò ni ijọ mẹwa. Faic an caibideil |