Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




1 Peteru 2:3 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 nísinsin yìí tí ẹ̀yin ti tọ́ ọ wò pé rere ni Olúwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

3 Ó ṣá ti hàn si yín pé olóore ni Oluwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

3 Bi ẹnyin ba ti tọ́ ọ wò pe, olõre li Oluwa:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




1 Peteru 2:3
8 Iomraidhean Croise  

Ta ni ọba ògo náà? Olúwa tí ó lágbára tí ó sì le, Olúwa gan an, tí ó lágbára ní ogun.


Tọ́ ọ wò kí o sì rí i wí pé Olúwa dára; ẹni ayọ̀ ni ọkùnrin náà tí ó gbẹ́kẹ̀lé ààbò nínú rẹ̀.


A ó tẹ́ ọkàn mi lọ́rùn bí ọlọ́ràá oúnjẹ; pẹ̀lú ètè ìyìn, ẹnu mi yóò yìn ọ́.


Àwọn tí ó mọ orúkọ rẹ yóò gbẹ́kẹ̀lé ọ, nítorí, Olúwa, kò kọ àwọn tó ń wá a sílẹ̀.


Bí igi ápù láàrín àwọn igi inú igbó, ni olólùfẹ́ mí láàrín àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Mo fi ayọ̀ jókòó ní abẹ́ òjìji rẹ̀, Èso rẹ̀ sì dùn mọ́ mi ní ẹnu.


Nítorí oore rẹ̀ tí tóbi tó, ẹwà rẹ̀ sì tí pọ̀! Ọkà yóò mú ọ̀dọ́mọkùnrin dárayá, àti ọtí wáìnì tuntun yóò mú àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú.


Ṣùgbọ́n nígbà tí inú rere àti ìfẹ́ Ọlọ́run Olùgbàlà wa farahàn,


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan