Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 4:42 - Bibeli Mimọ

42 Awọn ti a si kà ni idile awọn ọmọ Merari, nipa idile wọn, gẹgẹ bi ile baba wọn,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

42 Àwọn tí a kà ninu àwọn ọmọ Merari, ní ìdílé-ìdílé gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

42 Wọ́n ka àwọn ọmọ Merari nípa ìdílé àti ilé baba wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 4:42
4 Iomraidhean Croise  

Ọmọ Mahli, ọmọ Muṣi ọmọ Merari, ọmọ Lefi,


Ati fun awọn alufa ti a kọ sinu iwe nipa ile baba wọn, ati awọn ọmọ Lefi, lati ẹni ogun ọdun ati jù bẹ̃ lọ, ninu ilana wọn, nipa ipa wọn:


Wọnyi li awọn ti a kà ni idile awọn ọmọ Gerṣoni, gbogbo awọn ti o ṣe iṣẹ-ìsin ninu agọ́ ajọ, ti Mose ati Aaroni kà gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA.


Lati ẹni ọgbọ̀n ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, ani titi di ẹni ãdọta ọdún, gbogbo ẹniti o wọ̀ inu iṣẹ-ìsin na, fun iṣẹ ninu agọ́ ajọ,


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan