Numeri 4:13 - Bibeli Mimọ13 Ki nwọn ki o si kó ẽru kuro lori pẹpẹ, ki nwọn ki o si nà aṣọ elesè-aluko kan bò o. Faic an caibideilYoruba Bible13 Wọn óo kó eérú kúrò lórí pẹpẹ, wọn óo fi aṣọ elése àlùkò bò ó. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 “Kí wọn ó kó eérú kúrò lórí pẹpẹ idẹ, kí wọn ó sì tẹ́ aṣọ aláwọ̀ àlùkò lé e lórí. Faic an caibideil |