Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 26:13 - Bibeli Mimọ

13 Ti Sera, idile Sera: ti Ṣaulu, idile Ṣaulu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

13 ìdílé Sera ati ti Ṣaulu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 ti Sera, ìdílé Sera; tí Saulu, ìdílé Saulu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 26:13
6 Iomraidhean Croise  

Ati awọn ọmọ Simeoni; Jemueli, ati Jamini, ati Ohadi, ati Jakini, ati Sohari, ati Ṣaulu, ọmọ obinrin ara Kenaani kan.


Olori ogun kẹjọ fun oṣù kẹjọ ni Sibbekai ara Huṣati ti awọn ara Sarehi: ẹgbã mejila li o si wà ninu ẹgbẹ tirẹ̀.


Olori ogun kẹwa fun oṣù kẹwa ni Maharai ara Netofa, ti awọn ara Sarehi: ẹgbã mejila li o si wà ninu ẹgbẹ tirẹ̀.


Awọn ọmọ Simeoni bi idile wọn: ti Nemueli, idile Nemueli: ti Jamini, idile Jamini: ti Jakini, idile Jakini:


Wọnyi ni idile awọn ọmọ Simeoni, ẹgba mọkanla o le igba.


O si mú idile Juda wá; a si mu idile Sera: o si mú idile Sera wá li ọkunrin kọkan; a si mú Sabdi:


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan