Numeri 24:23 - Bibeli Mimọ23 O si bẹ̀rẹsi owe rẹ̀, o si wipe, A, tani yio wà, nigbati Ọlọrun yio ṣe eyi! Faic an caibideilYoruba Bible23 Balaamu tún fi òwe sọ ọ̀rọ̀ wọnyi: “Ta ni yóo là nígbà tí Ọlọrun bá ṣe nǹkan wọnyi? Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Nígbà náà ni ó bẹ̀rẹ̀ òwe rẹ̀: “Háà, ta ni ó lè yè nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe èyí? Faic an caibideil |