Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 24:21 - Bibeli Mimọ

21 O si wò awọn ara Keni, o si bẹ̀rẹsi owe rẹ̀, o si wipe, Agbara ni ibujoko rẹ̀, iwọ si tẹ́ itẹ́ rẹ sinu okuta.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

21 Nígbà tí ó wo àwọn ará Keni, ó fi òwe sọ̀rọ̀ nípa wọn báyìí pé: “Ibi ìpamọ́ tí ẹ̀ ń gbé dàbí ìtẹ́ tí ó wà lórí àpáta gíga.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Nígbà náà ní ó rí ará Keni ó sì bẹ̀rẹ̀ òwe: “Ibùgbé rẹ ní ààbò, ìtẹ́ rẹ ni a tò sínú àpáta;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 24:21
4 Iomraidhean Croise  

Awọn enia Keni, ati awọn enia Kenissi, ati awọn enia Kadmoni,


Nigbana ni mo wipe, emi o kú ninu itẹ mi, emi o si mu ọjọ mi pọ̀ si i bi iyanrin (bi ọjọ ti ẹiyẹ Feniksi).


Awọn ọmọ Keni, ana Mose, si bá awọn ọmọ Juda gòke lati ilu ọpẹ lọ si aginjù Juda, ni gusù Aradi; nwọn si lọ, nwọn si mbá awọn enia na gbé.


Saulu si wi fun awọn Keniti pe, Ẹ lọ, yẹra kuro larin awọn ara Amaleki, ki emi ki o má ba run nyin pẹlu wọn: nitoripe ẹnyin ṣe ore fun gbogbo awọn ọmọ Israeli nigbati nwọn goke ti Egipti wá. Awọn Keniti yẹra kuro larin Amaleki.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan