Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 21:12 - Bibeli Mimọ

12 Lati ibẹ̀ lọ nwọn ṣí, nwọn si dó si afonifoji Seredi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

12 Wọ́n gbéra láti ibẹ̀, wọ́n lọ pa àgọ́ sí àfonífojì Seredi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti gbéra wọ́n sì pa ibùdó ní Àfonífojì Seredi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 21:12
4 Iomraidhean Croise  

Nwọn si ṣi lati Obotu lọ, nwọn si dó si Iye-abarimu, li aginjù ti mbẹ niwaju Moabu, ni ìha ìla-õrùn.


Nwọn si ṣí kuro ni Iyimu, nwọn si dó si Dibon-gadi.


Ẹ dide, ẹ mú ọ̀na nyin pọ̀n, ki ẹ si gòke odò Arnoni: wò o, emi fi Sihoni ọmọ Amori, ọba Heṣboni lé ọ lọwọ, ati ilẹ rẹ̀: bẹ̀rẹsi gbà a, ki o si bá a jagun.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan