Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 21:10 - Bibeli Mimọ

10 Awọn ọmọ Israeli si ṣi siwaju, nwọn si dó ni Obotu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

10 Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò níbẹ̀, wọ́n pa àgọ́ wọn sí Obotu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Àwọn ọmọ Israẹli tẹ̀síwájú wọ́n sì péjọ sí Obotu.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 21:10
2 Iomraidhean Croise  

Nwọn si ṣi lati Obotu lọ, nwọn si dó si Iye-abarimu, li aginjù ti mbẹ niwaju Moabu, ni ìha ìla-õrùn.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan