Numeri 16:12 - Bibeli Mimọ12 Mose si ranṣẹ pè Datani ati Abiramu, awọn ọmọ Eliabu: nwọn si wipe, Awa ki yio gòke wá: Faic an caibideilYoruba Bible12 Mose bá ranṣẹ lọ pe Datani ati Abiramu, àwọn ọmọ Eliabu, ṣugbọn wọ́n kọ̀ wọn kò wá. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Mose sì ránṣẹ́ sí Datani àti Abiramu àwọn ọmọ Eliabu. Ṣùgbọ́n wọ́n wí pé “Àwa kò ní í wá! Faic an caibideil |