Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 13:6 - Bibeli Mimọ

6 Ninu ẹ̀ya Juda, Kalebu ọmọ Jefunne.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

6 láti inú ẹ̀yà Juda, ó rán Kalebu, ọmọ Jefune;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 láti inú ẹ̀yà Juda, Kalebu ọmọ Jefunne;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 13:6
16 Iomraidhean Croise  

Ati awọn ọmọ Kalebu ọmọ Jefunne; Iru, Ela, ati Naamu: ati awọn ọmọ Ela, ani Kenasi.


Kalebu si pa awọn enia lẹnu mọ́ niwaju Mose, o si wipe, Ẹ jẹ ki a gòke lọ lẹ̃kan, ki a si gbà a; nitoripe awa le ṣẹ́ ẹ.


Ninu ẹ̀ya Simeoni, Ṣafati ọmọ Hori.


Ninu ẹ̀ya Issakari, Igali ọmọ Josefu.


Ṣugbọn Kalebu iranṣẹ mi, nitoriti o ní ọkàn miran ninu rẹ̀, ti o si tẹle mi mọtimọti, on li emi o múlọ sinu ilẹ na nibiti o ti rè; irú-ọmọ rẹ̀ ni yio si ní i.


Ẹnyin ki yio dé inu ilẹ na, ti mo ti bura lati mu nyin gbé inu rẹ̀, bikoṣe Kalebu ọmọ Jefunne, ati Joṣua ọmọ Nuni.


Ṣugbọn Joṣua ọmọ Nuni, ati Kalebu ọmọ Jefunne, ninu awọn ọkunrin na ti o rìn ilẹ na lọ, wà lãye.


Ati Joṣua ọmọ Nuni ati Kalebu ọmọ Jefunne, ti o wà ninu awọn ti o ṣe amí ilẹ na, fà aṣọ wọn ya:


Nitoriti OLUWA ti wi fun wọn pe, Kíku ni nwọn o kú li aginjù. Kò si kù ọkunrin kan ninu wọn, bikoṣe Kalebu ọmọ Jefunne, ati Joṣua ọmọ Nuni.


Orukọ awọn ọkunrin na si ni wọnyi: ni ẹ̀ya Juda, Kalebu ọmọ Jefunne.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan