Numeri 13:11 - Bibeli Mimọ11 Ninu ẹ̀ya Josefu, eyinì ni, ninu ẹ̀ya Manasse, Gadi ọmọ Susi. Faic an caibideilYoruba Bible11 láti inú ẹ̀yà Josẹfu, tí í ṣe ẹ̀yà Manase, ó rán Gadi, ọmọ Susi; Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Láti inú ẹ̀yà Manase, (ẹ̀yà Josẹfu), Gaddi ọmọ Susi; Faic an caibideil |