Numeri 11:3 - Bibeli Mimọ3 O si pè orukọ ibẹ̀ na ni Tabera: nitoriti iná OLUWA jó lãrin wọn. Faic an caibideilYoruba Bible3 Wọ́n pe orúkọ ibẹ̀ ní Tabera, nítorí níbẹ̀ ni iná OLUWA ti jó láàrin wọn. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní3 Wọ́n sì ń pe ibẹ̀ ní Tabera nítorí pé, iná láti ọ̀dọ̀ Olúwa jó láàrín wọn. Faic an caibideil |