Numeri 10:16 - Bibeli Mimọ16 Olori ogun ẹ̀ya awọn ọmọ Sebuluni ni Eliabu ọmọ Heloni. Faic an caibideilYoruba Bible16 Olórí ẹ̀yà Sebuluni sì ni Eliabu ọmọ Heloni. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Eliabu ọmọ Heloni ni ọ̀gágun ni ìpín ti ẹ̀yà Sebuluni. Faic an caibideil |