Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:15 - Bibeli Mimọ

15 Ti Naftali; Ahira ọmọ Enani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

15 Ahira ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Nafutali.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Láti ọ̀dọ̀ Naftali, Ahira ọmọ Enani.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:15
5 Iomraidhean Croise  

Ti Gadi; Eliasafu ọmọ Deueli.


Wọnyi li awọn ti a yàn ninu ijọ, olori ẹ̀ya awọn baba wọn, awọn olori ẹgbẹgbẹrun ni Israeli.


Ati olori ogun ẹ̀ya awọn ọmọ Naftali ni Ahira ọmọ Enani.


Ati ẹ̀ya Naftali: Ahira ọmọ Enani yio si jẹ́ olori awọn ọmọ Naftali:


Li ọjọ́ kejila Ahira ọmọ Enani, olori awọn ọmọ Naftali:


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan