Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Marku 10:3 - Bibeli Mimọ

3 O si dahùn o si wi fun wọn pe, Aṣẹ kini Mose pa fun nyin?

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

3 Ó dá wọn lóhùn pé, “Kí ni Mose pa láṣẹ fun yín?”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Kí ni Mose pàṣẹ fún un yín?”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Marku 10:3
6 Iomraidhean Croise  

Si ofin ati si ẹri: bi nwọn kò ba sọ gẹgẹ bi ọ̀rọ yi, nitoriti kò si imọlẹ ninu wọn ni.


Awọn Farisi si tọ̀ ọ wá, nwọn ndán a wò, nwọn si bi i lẽre, wipe, O tọ́ fun ọkunrin ki o fi aya rẹ̀ silẹ?


Nwọn si wipe, Mose yọda fun wa lati kọ iwe ikọsilẹ fun u, ki a si fi i silẹ.


Si kiyesi i, amofin kan dide, o ndán a wò, o ni, Olukọni, kili emi o ṣe ki emi ki o le jogún iyè ainipẹkun?


Ẹnyin nwá inu iwe-mimọ́ nitori ẹnyin rò pe ninu wọn li ẹnyin ni ìye ti kò nipẹkun; wọnyi si li awọn ti njẹri mi.


Ẹ wi fun mi, ẹnyin ti nfẹ wà labẹ ofin, ẹ kò ha gbọ́ ofin?


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan