Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Luku 3:6 - Bibeli Mimọ

6 Gbogbo enia ni yio si ri igbala Ọlọrun.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

6 Gbogbo eniyan ni yóo rí ìgbàlà Ọlọrun.’ ”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Gbogbo ènìyàn ni yóò sì rí ìgbàlà Ọlọ́run.’ ”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Luku 3:6
9 Iomraidhean Croise  

A o si fi ogo Oluwa hàn, gbogbo ẹran-ara ni yio jùmọ ri i: nitori ẹnu Oluwa li o sọ ọ.


O si wipe, O ṣe ohun kekere ki iwọ ṣe iranṣẹ mi, lati gbe awọn ẹyà Jakobu dide, ati lati mu awọn ipamọ Israeli pada: emi o si fi ọ ṣe imọlẹ awọn Keferi, ki iwọ ki o le ṣe igbala mi titi de opin aiye.


Oluwa ti fi apá mimọ́ rẹ̀ hàn li oju gbogbo awọn orilẹ-ède; gbogbo opin aiye yio si ri igbala Ọlọrun wa.


O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si gbogbo aiye, ki ẹ si ma wasu ihinrere fun gbogbo ẹda.


Nitori kò si ìyatọ ninu Ju ati Hellene: nitori Oluwa kanna l'Oluwa gbogbo wọn, o si pọ̀ li ọrọ̀ fun gbogbo awọn ti nkepè e.


Ṣugbọn mo ni, Nwọn kò ha gbọ́ bi? Bẹni nitõtọ, Ohùn wọn jade lọ si gbogbo ilẹ, ati ọ̀rọ wọn si opin ilẹ aiye.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan