Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Luku 19:1 - Bibeli Mimọ

1 JESU si wọ̀ Jeriko lọ, o si nkọja lãrin rẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

1 Nígbà tí Jesu dé Jẹriko, ó ń la ìlú náà kọjá.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 Jesu sì wọ Jeriko lọ, ó sì ń kọjá láàrín rẹ̀.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Luku 19:1
7 Iomraidhean Croise  

Li ọjọ rẹ̀ ni Hieli, ara Beteli, kọ́ Jeriko: o fi ipilẹ rẹ̀ le ilẹ ni Abiramu, akọbi rẹ̀, o si gbé awọn ilẹkun ibode rẹ̀ kọ́ ni Segubu abikẹhin rẹ̀, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa, ti o ti ipa Joṣua, ọmọ Nuni sọ.


Nwọn si wá si Jeriko: bi o si ti njade kuro ni Jeriko pẹlu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, ati ọ̀pọ awọn enia, Bartimeu afọju, ọmọ Timeu, joko lẹba ọ̀na, o nṣagbe.


O si ṣe, bi on ti sunmọ Jeriko, afọju kan joko lẹba ọ̀na o nṣagbe:


Si kiyesi i, ọkunrin kan wà ti a npè ni Sakeu, o si jẹ olori agbowode kan, o si jẹ ọlọrọ̀.


JOṢUA ọmọ Nuni si rán ọkunrin meji jade lati Ṣittimu yọ lọ ṣe amí, wipe, Ẹ lọ iwò ilẹ na, ati Jeriko. Nwọn si lọ, nwọn si dé ile panṣaga kan, ti a npè ni Rahabu, nwọn si wọ̀ nibẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan