Luku 13:10 - Bibeli Mimọ10 O si nkọ́ni ninu sinagogu kan li ọjọ isimi. Faic an caibideilYoruba Bible10 Jesu ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́ ninu ilé ìpàdé kan ní Ọjọ́ Ìsinmi. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Ó sì ń kọ́ni nínú Sinagọgu kan ní ọjọ́ ìsinmi. Faic an caibideil |