Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Joṣua 4:16 - Bibeli Mimọ

16 Paṣẹ fun awọn alufa ti o rù apoti ẹri nì pe, ki nwọn ki o ti inu Jordani jade.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

16 “Pàṣẹ fún àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Ẹ̀rí pé kí wọ́n jáde kúrò ninu odò Jọdani.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 “Pàṣẹ fún àwọn àlùfáà tí o ń ru àpótí ẹ̀rí, kí wọn kí ó jáde kúrò nínú odò Jordani.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Joṣua 4:16
5 Iomraidhean Croise  

OLUWA si wi fun Joṣua pe,


Nitorina Joṣua paṣẹ fun awọn alufa wipe, Ẹ ti inu Jordani jade.


A si ṣí tẹmpili Ọlọrun silẹ li ọrun, a si ri apoti majẹmu ninu tẹmpili rẹ̀: mànamána si kọ, a si gbọ ohùn, ãrá si san, ìṣẹlẹ si ṣẹ̀, yinyín nla si bọ.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan