Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Joṣua 19:2 - Bibeli Mimọ

2 Nwọn si ní Beeri-ṣeba, tabi Ṣeba, ati Molada, ni ilẹ-iní wọn;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

2 Àwọn ìlú tí ó wà ninu ilẹ̀ tí wọ́n pín fún wọn nìyí: Beeriṣeba, Ṣeba, Molada;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Lára ìpín wọn ní: Beerṣeba (tàbí Ṣeba), Molada,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Joṣua 19:2
8 Iomraidhean Croise  

Abrahamu si dide ni kutukutu owurọ̀, o mu àkara ati ìgo omi kan, o fi fun Hagari, o gbé e lé e li ejika, ati ọmọ na, o si lé e jade: on si lọ, o nrìn kakiri ni ijù Beer-ṣeba.


Nitorina li o ṣe pè ibẹ̀ na ni Beer-ṣeba; nitori nibẹ̀ li awọn mejeji gbé bura.


Amamu, ati Ṣema, ati Molada;


Ati Hasari-ṣuali, ati Beeri-ṣeba, ati Bisi-otia;


IPÍN keji yọ fun Simeoni, ani fun ẹ̀ya awọn ọmọ Simeoni gẹgẹ bi idile wọn; ilẹ-iní wọn si wà lãrin ilẹ-iní awọn ọmọ Juda.


Ati Hasari-ṣuali, ati Bala, ati Esemu;


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan