Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Joṣua 15:57 - Bibeli Mimọ

57 Kaini, Gibea, ati Timna; ilu mẹwa pẹlu ileto wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

57 Kaini, Gibea, ati Timna, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹ́wàá.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

57 Kaini, Gibeah àti Timna: ìlú mẹ́wàá àti àwọn ìletò wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Joṣua 15:57
8 Iomraidhean Croise  

Nigbati ọjọ́ si npẹ́, ọmọbinrin Ṣua, aya Juda kú; Judah si gbipẹ̀, o si tọ̀ awọn olurẹrun agutan rẹ̀, lọ si Timnati, on ati Hira ọ̀rẹ́ rẹ̀, ara Adullamu.


A si wi fun Tamari pe, Kiyesi i, baba ọkọ rẹ lọ si Timnati lati rẹrun agutan rẹ̀.


On si bi Ṣaafa baba Madmana, Ṣefa baba Makbena, ati baba Gibea: ọmọbinrin Kalebu si ni Aksa.


EYI li ọ̀rọ Oluwa ti o tọ̀ Jeremiah wá nipa ti ọdá.


Àla na yi lati Baala lọ si ìha ìwọ-õrùn si òke Seiri, o si kọja lọ si ẹba òke Jearimu (ti ṣe Kesaloni), ni ìha ariwa, o si sọkalẹ lọ si Beti-ṣemeṣi, o si kọja lọ si Timna:


Ati Jesreeli, ati Jokdeamu, ati Sanoa;


Halhulu, Beti-suru, ati Gedori;


Ati Eloni, ati Timna, ati Ekroni;


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan