Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 8:13 - Bibeli Mimọ

13 Nitorina awọn Farisi wi fun u pe, Iwọ njẹri ara rẹ; ẹrí rẹ kì iṣe otitọ.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

13 Àwọn Farisi sọ fún un pé, “Ò ń jẹ́rìí ara rẹ, ẹ̀rí rẹ kò jámọ́ nǹkankan.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 Nítorí náà àwọn Farisi wí fún un pé, “Ìwọ ń jẹ́rìí ara rẹ; ẹ̀rí rẹ kì í ṣe òtítọ́.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 8:13
2 Iomraidhean Croise  

Nigbati nwọn si dì i loju, nwọn lù u niwaju, nwọn mbi i pe, Sọtẹlẹ, tani lù ọ nì?


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan