Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 6:16 - Bibeli Mimọ

16 Nigbati alẹ si lẹ, awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ lọ sinu okun.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

16 Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí èbúté,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 Nígbà tí alẹ́ sì lẹ́, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí Òkun.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 6:16
3 Iomraidhean Croise  

Nigbati alẹ si lẹ, ọkọ̀ si wà larin okun, on nikan si wà ni ilẹ.


A si pè Jesu ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pẹlu, si ibi igbeyawo.


Nwọn si bọ sinu ọkọ̀, nwọn si rekọja okun lọ si Kapernaumu. Okunkun si ti kùn, Jesu kò si ti ide ọdọ wọn.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan