4 On kò si le ṣaima kọja lãrin Samaria.
4 Ó níláti gba ààrin ilẹ̀ Samaria kọjá.
4 Òun sì ní láti kọjá láàrín Samaria.
O si ṣe, bi o ti nlọ si Jerusalemu, o kọja larin Samaria on Galili.
O si dahùn wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi nwá mi kiri? ẹnyin kò mọ pe, emi kò le ṣàima wà nibi iṣẹ Baba mi?
Ọjọ aiwukara pé, nigbati nwọn kò le ṣe aiṣẹbọ irekọja.