Johanu 2:3 - Bibeli Mimọ3 Nigbati waini si tan, iya Jesu wi fun u pe, Nwọn kò ni waini. Faic an caibideilYoruba Bible3 Nígbà tí ọtí tán, ìyá Jesu sọ fún un pé, “Wọn kò ní ọtí mọ́!” Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní3 Nígbà tí wáìnì sì tán, ìyá Jesu wí fún un pé, “Wọn kò ní wáìnì mọ́.” Faic an caibideil |