Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 19:1 - Bibeli Mimọ

1 NITORINA ni Pilatu mu Jesu, o si nà á.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

1 Nígbà náà ni Pilatu mú Jesu, ó ní kí wọ́n nà án.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 Nítorí náà ni Pilatu mú Jesu, ó sì nà án.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 19:1
16 Iomraidhean Croise  

Awọn awalẹ̀ walẹ si ẹhin mi: nwọn si la aporo wọn gigun.


Mo fi ẹ̀hìn mi fun awọn aluni, ati ẹ̀rẹkẹ mi fun awọn ti ntú irun: emi kò pa oju mi mọ́ kuro ninu itìju ati itutọ́ si.


Ṣugbọn a ṣá a li ọgbẹ nitori irekọja wa, a pa a li ara nitori aiṣedede wa; ìna alafia wa wà lara rẹ̀, ati nipa ìna rẹ̀ li a fi mu wa lara da.


Nwọn o si fà a le awọn keferi lọwọ lati fi i ṣe ẹlẹyà, lati nà a, ati lati kàn a mọ agbelebu: ni ijọ kẹta yio si jinde.


Nitorina ẹ kiyesi i, Emi rán awọn wolĩ, ati amoye, ati akọwe si nyin: omiran ninu wọn li ẹnyin ó pa, ti ẹnyin ó si kàn mọ agbelebu; ati omiran ninu wọn li ẹnyin o nà ni sinagogu nyin, ti ẹnyin o si ṣe inunibini si lati ilu de ilu:


Nwọn o si nà a, nwọn o si pa a: ni ijọ kẹta yio si jinde.


Njẹ emi ó nà a, emi ó si jọwọ rẹ̀ lọwọ lọ.


Nwọn tilẹ̀ kirimọ́ igbe nla, nwọn nfẹ ki a kàn a mọ agbelebu. Ohùn ti wọn ati ti awọn olori alufa bori tirẹ̀.


Nigba marun ni mo gbà paṣan ogoji dín kan lọwọ awọn Ju.


Awọn ẹlomiran si ri idanwò ti ẹsín, ati ti ìnà, ati ju bẹ̃ lọ ti ìde ati ti tubu:


Ẹniti on tikararẹ̀ fi ara rẹ̀ rù ẹ̀ṣẹ wa lori igi, pe ki awa ki o le di okú si ẹ̀ṣẹ ki a si di ãye si ododo: nipa ìnà ẹniti a mu nyin larada.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan