Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 16:9 - Bibeli Mimọ

9 Niti ẹ̀ṣẹ, nitoriti nwọn kò gbà mi gbọ́;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

9 Wọ́n ti ṣìnà ninu èrò wọn nípa ẹ̀ṣẹ̀ nítorí pé wọn kò gbà mí gbọ́.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 ní ti ẹ̀ṣẹ̀, nítorí tí wọn kò gbà mí gbọ́;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 16:9
18 Iomraidhean Croise  

Ẹniti o ba gbagbọ́, ti a ba si baptisi rẹ̀ yio là; ṣugbọn ẹniti kò ba gbagbọ́ yio jẹbi.


Nigbati on ba si de, yio fi òye yé araiye niti ẹ̀ṣẹ, ati niti ododo, ati niti idajọ:


Emi si ti wà lãye laisi ofin nigbakan rì: ṣugbọn nigbati ofin de, ẹ̀ṣẹ sọji, emi si kú.


Bi mo tilẹ jẹ asọ ọ̀rọ-odì lẹkan rí, ati oninunibini, ati elewu enia: ṣugbọn mo ri ãnu gbà, nitoriti mo ṣe e li aimọ̀ ninu aigbagbọ.


Ẹ kiyesara, ará, ki ọkàn buburu ti aigbagbọ́ ki o máṣe wà ninu ẹnikẹni nyin, ni lilọ kuro lọdọ Ọlọrun alãye.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan