Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 13:30 - Bibeli Mimọ

30 Nigbati o si ti gbà òkele na tan, o jade lojukanna: oru si ni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

30 Lẹsẹkẹsẹ tí Judasi ti gba òkèlè náà tán, ó jáde lọ. Ilẹ̀ ti ṣú nígbà náà.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Nígbà tí ó sì ti gbà òkèlè náà tan, ó jáde lójúkan náà àkókò náà si jẹ òru.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 13:30
6 Iomraidhean Croise  

Nitoriti nwọn kì isùn bikoṣepe nwọn hùwa buburu; orun wọn a si dá, bikoṣepe nwọn ba mu enia ṣubu.


Ẹsẹ wọn sare si ibi, nwọn si yara lati tajẹ̀ alaiṣẹ̀ silẹ: èro wọn èro ibi ni; ibajẹ ati iparun mbẹ ni ipa wọn.


Nigbati emi wà pẹlu nyin lojojumọ ni tẹmpili, ẹnyin ko nà ọwọ́ mu mi: ṣugbọn akokò ti nyin li eyi, ati agbara òkunkun.


Nitorina Jesu dahùn pe, On na ni, ẹniti mo ba fi òkele fun nigbati mo ba fi run. Nigbati o si fi i run tan, o fifun Judasi Iskariotu ọmọ Simoni.


Ẹsẹ wọn yara lati ta ẹ̀jẹ silẹ:


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan