Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 11:23 - Bibeli Mimọ

23 Jesu wi fun u pe, Arakunrin rẹ yio jinde.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

23 Jesu wí fún un pé, “Arakunrin rẹ yóo jí dìde.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Jesu wí fún un pé, “Arákùnrin rẹ yóò jíǹde.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 11:23
4 Iomraidhean Croise  

Ṣugbọn nisisiyi na, mo mọ̀ pe, ohunkohun ti iwọ ba bère lọwọ Ọlọrun, Ọlọrun yio fifun ọ.


Marta wi fun u pe, Mo mọ̀ pe yio jinde li ajinde nigbẹhin ọjọ.


Jesu wi fun u pe, Emi kò ti wi fun ọ pe, bi iwọ ba gbagbọ́, iwọ o ri ogo Ọlọrun?


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan