Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 1:23 - Bibeli Mimọ

23 O wipe, Emi li ohùn ẹni ti nkigbe ni ijù, Ẹ ṣe ki ọ̀na Oluwa tọ́, gẹgẹ bi woli Isaiah ti wi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

23 Ó bá dáhùn gẹ́gẹ́ bí wolii Aisaya ti sọ pé: “Èmi ni ‘ohùn ẹni tí ń kígbe ninu aṣálẹ̀ pé: Ẹ ṣe ọ̀nà tí ó tọ́ fún Oluwa.’ ”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Johanu sì fi ọ̀rọ̀ wòlíì Isaiah fún wọn ní èsì pé, “Èmi ni ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù, ‘Ẹ ṣe ọ̀nà Olúwa ní títọ́.’ ”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 1:23
9 Iomraidhean Croise  

Nitori eyi li ẹniti woli Isaiah sọ ọ̀rọ rẹ̀, wipe, Ohùn ẹnikan ti nkigbe ni ijù, Ẹ tún ọ̀na Oluwa ṣe, ẹ ṣe oju-ọ̀na rẹ̀ tọ́.


Ohùn ẹnikan ti nkigbe ni ijù, Ẹ tún ọ̀na Oluwa ṣe, ẹ ṣe oju ọ̀na rẹ̀ tọ́.


Nitorina nwọn wi fun u pe, Tani iwọ iṣe? ki awa ki o le fi èsi fun awọn ti o rán wa. Kili o wi ni ti ara rẹ?


Awọn ti a rán si jẹ ninu awọn Farisi.


Ẹnyin tikaranyin jẹri mi, pe mo wipe, Emi kì iṣe Kristi na, ṣugbọn pe a rán mi ṣiwaju rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan