Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Gẹnẹsisi 10:3 - Bibeli Mimọ

3 Ati awọn ọmọ Gomeri, Aṣkenasi, ati Rifati, ati Togarma.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣikenasi, Rifati, ati Togama.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifàti àti Togarma.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Gẹnẹsisi 10:3
4 Iomraidhean Croise  

Ati awọn ọmọ Gomeri; Aṣkenasi, ati Rifati, ati Togarma.


Ẹ gbe asia soke ni ilẹ na, fọn ipè lãrin awọn orilẹ-ède, sọ awọn orilẹ-ède di mimọ́ sori rẹ̀, pè awọn ijọba Ararati, Minni, ati Aṣkinasi sori rẹ̀, yàn balogun sori rẹ̀, mu awọn ẹṣin wá gẹgẹ bi ẹlẹnga ẹlẹgun.


Awọn ti ile Togarma fi ẹṣin, ati ẹlẹṣin ati ibaka ṣòwo li ọjà rẹ.


Gomeri, ati gbogbo ogun rẹ̀; ile Togarma ti ihà ariwa, ati gbogbo ogun rẹ̀: enia pupọ̀ pẹlu rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan